Happy birthday Paito wa!
Olu so Promax G!!
Pope Tee gbo gbo Canada!!!
Oluwa seun o -Mo ba yin yo o, Ema ri Odun Mo dun, Ayo yin a dale o, eku ise Oluwa, ebun ororo yin o ni gbe o, Ede fi Orun se ere je o. Amin.
Eku orire ayeye Ogoji Odun.
Ire ati aanu 🙏😘.
Leave Your Comment